Aláìní-olùfaragbá (Victimless)
Ó ń ṣàpèjúwe ìṣe tí kò pa ẹnikẹ́ni tí kò fẹ́ kí a ṣe é sí i lára. Bí a kò bá pa ẹnikẹ́ni lára lòdì sí ìfẹ́ rẹ̀, nígbà náà kò sí olùfaragbá tí kò sì sí ìwà-ọ̀daràn nítorí náà.